
King Sunny Adé – Ekilo Fomo Ode Mp3 Download
Ekilo Fomo Ode by King Sunny Adé Mp3 Download
Get this amazing new song titled Ekilo Fomo Ode by King Sunny Adé. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success and has been called one of the most influential musicians of all time. His song is available for streaming and downloading on all our platform.
Download & Stream Mp3 Below
Lyrics Of Ekilo Fomo Ode by King Sunny Adé
Awo re gungun lobirin le ṣe
Awo gẹlẹdẹ lobirin le mọ Bi obinrin fi oju doro, oro a gbeÉkilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Koma sesi fara ko odidan lojiji Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riruKonko jabẹlẹ
Kaluku l’omi se ti é Konko jabẹlẹ Kaluku l’omi se ti e Konko jabẹlẹ Kaluku l’omi se ti e Konko jabẹlẹ Kaluku l’omi se ti eKi àwon ṣe tiwọn
Ki ẹyin ṣe t’ẹyin Ki àwa ṣe t’awaKonko jabẹlẹ
Kaluku l’omi se ti eAmò ṣá
Ékilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn padoÉkilo f’ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Koma sesi fara ko odidan lojiji Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru
Leave a Reply