
King Sunny Adé – Ejire Ara Isokun Mp3 Download
Ejire Ara Isokun by King Sunny Adé Mp3 Download
Get this amazing new song titled Ejire Ara Isokun by King Sunny Adé. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success and has been called one of the most influential musicians of all time. His song is available for streaming and downloading on all our platform.
Download & Stream Mp3 Below
Lyrics of Ejire Ara Isokun by King Sunny Adé
Ejiré ara isokun omo edunjobi
N bá bi ejiré o, inu mi a dun o N bá bi ejiré o, inu mi a dun o Eru o ba mi o, rara o, rara o Aya o fo mi o, lati bi ejiré Ejiré dara, mo ni epo nile Mo ni ẹwà l’ọna oTaiye lolulu ijo loni
Ijo, ejire ijo l’owo, ijo N ba bi ejire ma ba jo Ijo, ejire ijo l’owo, ijo M bá bi ejire m bá yo dandan Ijo, ejire ijo l’owo, ijoOwo ile alakisa oso alakisa di alaso
Ijo, ejire ijo l’owo, ijo Owo ile alakisa oso alakisa di alaso Ijo, ejire ijo l’owo, ijo Owo ile olomo meji, o so do olomo meji di olomo merin Ijo, ejire ijo l’owo, ijo Omo meji jo ijo re Ijo, ejire ijo l’owo, ijo
Leave a Reply