
King Sunny Adé – Bole Ya Koya Mp3 Download
Bole Ya Koya by King Sunny Adé Mp3 Download
Get this amazing new song titled Bole Ya Koya by King Sunny Adé. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success and has been called one of the most influential musicians of all time. His song is available for streaming and downloading on all our platform.
Download & Stream Mp3 Below
Lyrics Of Bole Ya Koya by King Sunny Adé
Ika a p’onika o
Rere a b’ẹni rere Ika a p’onika o Rere a b’ẹni rere Ẹni gb’ẹkun gba l’ayé Aya rẹ a jẹ, ọmọ rẹ a jẹ Oun naa a wẹwẹ sẹ Ko gbọn bi ifá kò mọ’ ran bi ọpẹ lẹ (Oun naa a wẹwẹ sẹ) (Oun naa a wẹwẹ sẹ) Ko gbọn bi ifá kò mọ ran bi ọpẹ lẹ (Oun naa a wẹwẹ sẹ) (Oun naa a wẹwẹ sẹ)Apa okan o ju’kan l’ayé nbi ṣẹ
Af’eyi to ba g’ori bebé o Ko’soun t’adiyẹ t’ole f’ẹyẹ aṣa ṣe Ko’soun t’adiyẹ Ko’soun t’adiyẹ t’ole f’ẹyẹ aṣa ṣe Ko’soun t’adiyẹ Ko’soun t’adiyẹ t’ole f’ẹyẹ aṣa ṣe Yiyọ ẹmu o Bi t’odo kọ Ko’soun t’adiyẹ Ko’soun t’adiyẹ t’ole f’ẹyẹ aṣa ṣe Ko’soun t’adiyẹ Ko’soun t’adiyẹ t’ole f’ẹyẹ aṣa ṣe Ko’soun t’adiyẹ Ko’soun t’adiyẹ t’ole f’ẹyẹ aṣa ṣeAni yiyọ ẹmu o
Bi t’odo kọ Ko’soun t’adiyẹ Ko’soun t’adiyẹ t’ole f’ẹyẹ aṣa ṣe Ko’soun t’adiyẹ Ko’soun t’adiyẹ t’ole f’ẹyẹ aṣa ṣe Ko ma sòún t’adiyẹ to le f’ẹyẹ aṣa ṣe o Ko’soun t’adiyẹ Ko’soun t’adiyẹ t’ole f’ẹyẹ aṣa ṣeBole ya koya ye o(Bole ya koya)
B’o ba le ya koya ṣẹ (Bole ya koya) B’o ba le ya ko ma ya o (Bole ya koya) Ojo p’ewe ko ku(Bole ya koya) Ojo p’ewe ko ku(Bole ya koya) Mo m’ẹmu m’ẹmu mo da bi ẹmu (Bole ya koya) Mo m’ẹmu m’ẹmu mo da bi ẹmu (Bole ya koya) Mo m’ogurọ titi mo da bi ritu (Bole ya koya) Mo jo bẹbẹ titi ojo p’ewe ko ku (Bole ya koya) Ojo to pa bata-koto ko pa ju ri ti (Bole ya koya) Ojo p’ewe ko ku(Bole ya koya) Ojo p’ewe ko ku sẹ (Bole ya koya) Ojo p’ewe ko ku (Bole ya koya)Mo m’ẹmu m’ẹmu mo da bi ẹmu (Bole ya koya)
Mo m’ogurọ titi mo da bi ritu (Bole ya koya) Ojo p’ewe ko ku(Bole ya koya) Ojo p’ewe ko ku sẹ (Bole ya koya)
Leave a Reply