
King Sunny Adé – Sunny Koni Ku Mp3 Download
Sunny Koni Ku by King Sunny Adé Mp3 Download
Get this amazing new song titled Sunny Koni Ku by King Sunny Adé. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success and has been called one of the most influential musicians of all time. His song is available for streaming and downloading on all our platform.
Download & Stream Mp3 Below
Lyrics Of Sunny Koni Ku by King Sunny Adé
Koni ku o
Rọmọla Ofeṣe Koni ku o Sunny mi o ni ku o Rọmọla Ofeṣe Koni ku o Tori gunugun kii ku s’ewe O ṣe’wọ o Ẹnikan ki ba alágẹmọ labẹ ewe Bẹẹni, a kì ma rọ gidigba la lẹ odoKoni ku sẹ
Rọmọla Ofeṣe Koni ku oAdìyẹ yo, adìyẹ pogun
Wan l’adiye ro p’ọmọ rẹ Adìyẹ rọgbọn, adìyẹ pọgbọn Wan l’adiye ro p’ọmọ rẹ Wan binu gb’adiyẹ ta Wan f’owo ra’wo Awo y’ẹyin mẹfa O fi pa kan ṣoṣo Ọkan ṣoṣo girogiro Ọkan ṣoṣo l’ẹrin n ṣe gbo Ọkan ṣoṣo r’ẹfan ni sọdan Ọkan ṣoṣo l’ajanaku nimi gbo kiji-kiji-kijiAwa ti b’egun ja o
Aṣẹgun re’gungun Ati b’ọrìṣà já o Awa d’oriṣa kunlẹ bọ Awọn agbejọ ra lo f’ọlọrun ọba Bambaa ni baba n daẸni t’ọlọrun ba ti dá
Ko ṣe f’arawe Ko ṣe f’arawe Bamba ni n baba da wa o Ko ṣe f’arawe Ẹni tí Ọlọrun ba ti dá n nkọ Ko ṣe f’arawe Gbamugbamu jigijigi Ko ṣe f’arawe
Leave a Reply