
King Sunny Adé – S.K. Dada (Re-Mastered) Mp3 Download
S.K. Dada (Re-Mastered) by King Sunny Adé Mp3 Download
Get this amazing new song titled S.K. Dada (Re-Mastered) by King Sunny Adé. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success and has been called one of the most influential musicians of all time. His song is available for streaming and downloading on all our platform.
Download & Stream Mp3 Below
Lyrics Of S.K. Dada (Re-Mastered) by King Sunny Adé
Ìbàdàn mesi ọgọ
Oya ka lọ
Ìbàdàn mesi ọgọ
Oya ka lọ
Ka lọ j′ewurẹ j’ẹyan
Ka lọ j′ewurẹ j’ẹyan
Ojẹ tẹle mi ka lọ o
Oya o, oya o
Ni ile Abdulfatai ni
Fatai Daramọla
Importer and exporter tiwa ni
Baba Ṣakí
Baba Akeemu ni
Ẹtun rọkọ Yetunde
Ẹtun rọkọ Fausah
Ìbàdàn mesi ọgọ
Oya ka lọ
Ìbàdàn mesi ọgọ
Oya ka lọ
Ka lọ j’ewurẹ j′ẹyan
Ka lọ j′ewurẹ j’ẹyan
Ojẹ tẹle mi ka lọ o
Oya o, oya o
Ni ile Fatai ni
Oya ka lọ Oluyọle
Oya ka re Oluyọle o
Ile Abdulfatai o
Ẹwọ Tunde ọmọ Oṣodi mi
President
Ẹwo Sunday ọmọ Adigun
Ẹwo Ademọla Lawal mi ni
Ẹwo Sule Maito, magbadun ni tiẹ
Ìbàdàn ni mo ma
Emi o ma Layipo
Ìbàdàn la ma
A o mọ Layipo
Awo Kolawole
Ẹyin mi Atomoye Sanya
Ìbàdàn la ma
A o mọ Layipo
Ko jẹ nikan lowo rararararara(Ko jẹ nikan lowo)
Fatai (Ko jẹ nikan lowo)
Daramọla (Ko jẹ nikan lowo)
(Ko jẹ nikan lowo)
Leave a Reply