
King Sunny Adé – Kosun Tadie Mp3 Download
Kosun Tadie by King Sunny Adé Mp3 Download
Get this amazing new song titled Kosun Tadie by King Sunny Adé. Chief Sunday Adeniyi Adegeye MFR, known professionally as King Sunny Adé, is a Nigerian jùjú singer, songwriter, and multi-instrumentalist. He is regarded as one of the first African pop musicians to gain international success and has been called one of the most influential musicians of all time. His song is available for streaming and downloading on all our platform.
Download & Stream Mp3 Below
Lyrics Of Kosun Tadie by King Sunny Adé
Wan ran ‘mọ lọ’ja
Ko lo r’ori ọkà oni nọyin wa Wan ran ‘mọ lọ’ja Ko lo r’ori ọkà oni nọyin waItun meje, at’arẹ meje pẹlu adere meje
Wan wa gun pọ, wan ko m’ọṣẹ dudu Wan wa gbefun padi ẹ Padi ỌdẹnsonWan wa gbefun padi ẹ
(Padi Ọdẹnson) Wan wa gbefun padi ẹ (Padi Ọdẹnson)Oṣika ma ṣe’ka mọ o
(Ika a p’oni’ka o) Oṣika ma ṣe’ka mọ o (Ika a p’oni’ka o) Oṣika ma ṣe’ka mọ o (Ika a p’oni’ka o) Oṣika ma ṣe’ka mọ o (Ika a p’oni’ka o)Ika a p’oni’ka o
(Ika a p’oni’ka o)Ika a p’oni’ka o
(Rere a b’ẹni rere) Ika a p’oni’ka o (hee) (Rere a b’ẹni rere)Odaju
Ẹni gbẹkun gba laye Aya rẹ a jẹ, ọmọ rẹ a jẹ Oun naa a wẹwẹ sẹ
Leave a Reply